Aisaya 2:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Ilẹ̀ wọn kún fún oriṣa,wọ́n ń bọ iṣẹ́ ọwọ́ ara wọn,wọ́n ń wólẹ̀ fún ohun tí wọ́n fọwọ́ ara wọn ṣe.

Aisaya 2

Aisaya 2:1-17