Aisaya 19:8 BIBELI MIMỌ (BM)

Àwọn apẹja tí ń fi ìwọ̀ ninu odò Nailiyóo ṣọ̀fọ̀,wọn óo sì sọkún tẹ̀dùntẹ̀dùn;àwọn tí ń fi àwọ̀n pẹja yóo kérora.

Aisaya 19

Aisaya 19:5-14