Aisaya 19:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo odò wọn yóo máa rùn,gbogbo àwọn odò tí ó ṣàn wọ odò Naili ní Ijipti,ni yóo fà, tí yóo sì gbẹ:Gbogbo koríko odò yóo rà.

Aisaya 19

Aisaya 19:1-11