Aisaya 19:4 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn n óo fi Ijipti lé aláìláàánú akóniṣiṣẹ́ kan lọ́wọ́ìkà kan ni yóo sì jọba lé wọn lórí,bẹ́ẹ̀ ni Oluwa, OLUWA àwọn ọmọ ogun wí.

Aisaya 19

Aisaya 19:1-8