Aisaya 19:16 BIBELI MIMỌ (BM)

Tí ó bá di ìgbà náà, àwọn ará Ijipti yóo di obinrin. Wọn yóo máa gbọ̀n, fún ẹ̀rù, nígbà tí OLUWA àwọn ọmọ ogun bá gbá wọn mú.

Aisaya 19

Aisaya 19:9-19