Aisaya 18:6 BIBELI MIMỌ (BM)

Gbogbo wọn yóo wà nílẹ̀,wọn yóo di ìjẹ fún àwọn ẹyẹ orí òkè,ati àwọn ẹranko inú ìgbẹ́.Àwọn ẹyẹ yóo fi wọ́n ṣe oúnjẹ ní ìgbà ẹ̀ẹ̀rùn,àwọn ẹranko yóo fi wọ́n ṣe oúnjẹ jẹ ní ìgbà òtútù.

Aisaya 18

Aisaya 18:5-7