Ìlú olódi kò ní sí mọ́ ní Efuraimu,kò sì ní sí ìjọba mọ́ ní Damasku,àwọn tí wọ́n bá ṣẹ́kù ní Siriayóo sì dàbí ògo àwọn ọmọ Israẹli,OLUWA àwọn ọmọ ogun ló sọ bẹ́ẹ̀.