Aisaya 16:6 BIBELI MIMỌ (BM)

A ti gbọ́ ìròyìn ìgbéraga Moabu,bí ó ṣe ń ṣe àfojúdi tí ó sì ń sọ ìsọkúsọ:ṣugbọn lásán ni ìgbéraga rẹ̀.

Aisaya 16

Aisaya 16:1-8