Aisaya 14:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Máa sọkún, ìwọ ẹnubodè,kí ìwọ ìlú sì figbe ta.Ẹ̀yin ará Filistini, ẹ máa gbọ̀n jìnnìjìnnìnítorí pé àwọn ọmọ ogun kan ń rọ́ bọ̀ bí èéfín, láti ìhà àríwá,kò sí ọ̀kan ninu àwọn ọmọ ogun wọntí ó ń ṣe dìẹ̀dìẹ̀ bọ̀ lẹ́yìn.

Aisaya 14

Aisaya 14:23-32