Aisaya 14:3 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA bá fun yín ní ìsinmi kúrò ninu làálàá ati rògbòdìyàn ati iṣẹ́ àṣekára tí wọn ń fi tipá mu yín ṣe,

Aisaya 14

Aisaya 14:1-5