Aisaya 14:22 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA àwọn ọmọ ogun ní, “N óo gbógun tì wọ́n, n óo pa orúkọ Babiloni rẹ́ ati ìyókù àwọn eniyan tí ó wà ninu rẹ̀, ati arọmọdọmọ wọn.

Aisaya 14

Aisaya 14:18-29