Aisaya 13:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! Ọjọ́ OLUWA dé tán,tìkàtìkà pẹlu ìrúnú ati ibinu gbígbóná láti sọ ayé di ahoro,ati láti pa àwọn ẹlẹ́ṣẹ̀ inú rẹ̀ run.

Aisaya 13

Aisaya 13:8-15