Aisaya 13:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Wọ́n wá láti ilẹ̀ òkèèrè,láti ìpẹ̀kun ayé.OLUWA ń bọ̀ pẹlu àwọn ohun ìjà ibinu rẹ̀,tí yóo fi pa gbogbo ayé run.

Aisaya 13

Aisaya 13:1-12