Aisaya 13:17 BIBELI MIMỌ (BM)

Wò ó! N óo rú àwọn ará Media sókè sí wọn,àwọn tí wọn kò bìkítà fún fadakabẹ́ẹ̀ ni wọn kò ka wúrà sí.Wọn óo wá bá Babiloni jà.

Aisaya 13

Aisaya 13:14-20