Aisaya 13:1-2 BIBELI MIMỌ (BM)

1. Ìran tí Aisaya ọmọ Amosi rí sí Babiloni:

2. Ẹ ta àsíá ní orí òkè gíga,ẹ gbóhùn sókè sí wọn.Ẹ juwọ́, kí àwọn ológun gba ẹnu ibodè àwọn ọlọ́lá wọlé.

Aisaya 13