Aisaya 12:5 BIBELI MIMỌ (BM)

Ẹ kọ orin ìyìn sí OLUWAnítorí ó ṣe nǹkan tí ó lógo,jẹ́ kí èyí di mímọ̀ ní gbogbo ayé.

Aisaya 12

Aisaya 12:1-6