Aisaya 11:13 BIBELI MIMỌ (BM)

Owú jíjẹ Efuraimu yóo kúrò,a óo sì pa àwọn tí ń ni Juda lára run.Efuraimu kò gbọdọ̀ jowú Juda mọ́,bẹ́ẹ̀ ni Juda kò gbọdọ̀ ni Efuraimu lára mọ.

Aisaya 11

Aisaya 11:6-16