Aisaya 10:7 BIBELI MIMỌ (BM)

Ṣugbọn ọba Asiria kò pa irú ète yìí,kò sì ní irú èrò yìí lọ́kàn;gbogbo èrò ọkàn rẹ̀ ni láti pa ọpọlọpọ orílẹ̀-èdè run

Aisaya 10

Aisaya 10:2-17