Aisaya 10:22 BIBELI MIMỌ (BM)

Israẹli, bí àwọn eniyan rẹ tilẹ̀ pọ̀ bí iyanrìn etí òkun, díẹ̀ ninu wọn ni yóo pada, nítorí ìparun ti di òfin ó sì kún fún òdodo

Aisaya 10

Aisaya 10:18-29