Aisaya 10:18 BIBELI MIMỌ (BM)

OLUWA yóo pa àwọn igi ńlá inú igbó rẹ̀ run,yóo pa àwọn igi eléso ilẹ̀ rẹ́ tèsotèso,bí ìgbà tí àrùn bá gbẹ eniyan.

Aisaya 10

Aisaya 10:16-26