Aisaya 10:12 BIBELI MIMỌ (BM)

Nígbà tí OLUWA bá parí bírà tí ó ń dá ní òkè Sioni ati ní Jerusalẹmu,yóo fìyà jẹ ọba Asiria fún ìwà ìgbéraga ati àṣejù rẹ̀.

Aisaya 10

Aisaya 10:11-17