Aisaya 1:9 BIBELI MIMỌ (BM)

Bí kò bá ṣe pé OLUWA àwọn ọmọ ogun dá díẹ̀ sí ninu wa ni,à bá rí bí i Sodomu,à bá sì dàbí Gomora.

Aisaya 1

Aisaya 1:1-16