Aisaya 1:31 BIBELI MIMỌ (BM)

Alágbára yóo dàbí ògùṣọ̀,iṣẹ́ ọwọ́ rẹ̀ bí ìṣáná.Àwọn mejeeji ni yóo jóná pọ̀,kò sì ní sí ẹni tí yóo lè pa iná náà.

Aisaya 1

Aisaya 1:24-31