Aisaya 1:29 BIBELI MIMỌ (BM)

Ojú yóo tì yín, fún àwọn igi Oaku tí ẹ nífẹ̀ẹ́ láti máa bọ.Ojú yóo sì tì yín fún àwọn ọgbà oriṣa tí ẹ yàn.

Aisaya 1

Aisaya 1:24-30