Aisaya 1:24 BIBELI MIMỌ (BM)

Nítorí náà, OLUWA àwọn ọmọ ogun, Alágbára Israẹli ní:“N óo bínú sí àwọn ọ̀tá mi,n óo sì gbẹ̀san lára àwọn tí ó kórìíra mi.

Aisaya 1

Aisaya 1:15-31