Aisaya 1:21 BIBELI MIMỌ (BM)

Ìlú tí ó ti jẹ́ olódodo rí tí ń ṣe bí aṣẹ́wó,ìlú tí ó ti kún fún ẹ̀tọ́ ati òdodo rí, ti kún fún ìpànìyàn.

Aisaya 1

Aisaya 1:17-28