Sekaráyà 9:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Tírè sì mọ odi líle fún ara rẹ̀,ó sì kó fàdákà jọ bí èkuru,àti wúrà dáradára bí àfọ̀ ẹ̀rẹ̀ ìgboro.

Sekaráyà 9

Sekaráyà 9:1-4