Sekaráyà 6:12 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Sì sọ fún un pé: ‘Báyìí ni Olúwa àwọn ọmọ-ogún sọ wí pé, wo ọkùnrin náà ti orukọ rẹ̀ ń jẹ́ Ẹ̀ka; yóò sì yọ ẹ̀ka láti abẹ́ rẹ̀ wá, yóò si kọ́ tẹ́ḿpìlì Olúwa wa.

Sekaráyà 6

Sekaráyà 6:9-14