Sekaráyà 5:9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì gbé ojú mi sókè, mo sì wò, sì kíyèsí i, obìnrin méjì jáde wá, èfúùfù sì wá nínú ìyẹ́ wọn; nítorí wọ́n ní ìyẹ́ bí ìyẹ́ àkọ̀: Wọ́n sì gbé òṣùwọ̀n éfà náà dé àárin méjì ayé àti ọ̀run.

Sekaráyà 5

Sekaráyà 5:5-11