Sekaráyà 5:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ó sì wí fún mi pé, “Kí ni ìwọ rí?”Èmi sì dáhùn pé, “Mo rí ìwé-kíkà tí ń fò; gígùn rẹ̀ jẹ́ ogún ìgbọ̀nwọ́, ìbú rẹ̀ sì jẹ́ ìgbọ̀nwọ́ mẹ́wàá.”

Sekaráyà 5

Sekaráyà 5:1-10