Sekaráyà 4:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Igi ólífì méjì sì wà létí rẹ̀, ọ̀kan ní apá ọ̀tún àwokòtò náà, àti èkejì ní apá òsì rẹ̀.”

Sekaráyà 4

Sekaráyà 4:1-5