Sekaráyà 2:10 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kọrin kí o sì yọ̀, ìwọ ọmọbìnrin Síónì: Nítorí èmi ń bọ̀ àti pé èmi yóò sì gbé àárin rẹ,” ni Olúwa àwọn ọmọ-ogun wí.

Sekaráyà 2

Sekaráyà 2:3-13