Sekaráyà 13:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Ní ọjọ́ náà isun kan yóò sí sílẹ̀ fún ilé Dáfídì àti fún àwọn ará Jérúsálẹ́mù, láti wẹ̀ wọ́n mọ́ kúrò nínú ẹ̀ṣẹ̀ àti àìmọ́ wọn.

Sekaráyà 13

Sekaráyà 13:1-8