Sekaráyà 12:2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

“Kíyèsí í, èmi yóò ṣọ Jérúsálẹ́mù dí àgọ́ ìwárìrì sí gbogbo ènìyàn yíká, nígbà tí wọn yóò dó ti Júdà àti Jérúsálẹ́mù.

Sekaráyà 12

Sekaráyà 12:1-10