Sekaráyà 11:3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Gbọ́ ohun igbe àwọn olùṣọ́-àgùntàn;ògo wọn bàjẹ́;gbọ́ ohùn bíbú àwọn ọmọ kìnnìúnnítorí ògo Jódánì bàjẹ́.

Sekaráyà 11

Sekaráyà 11:1-13