Sekaráyà 11:14 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Mo sì ṣẹ́ ọ̀pá mi kejì, àní Àmùrè, sí méjì, kí èmi lè ya ìbátan tí ó wà láàrin Júdà àti láàrin Íṣírẹ́lì.

Sekaráyà 11

Sekaráyà 11:11-16