Sekaráyà 1:15 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Èmi sì bínú púpọ̀púpọ̀ si àwọn orílẹ̀-èdè tí o gbé jẹ́ẹ: nítorí nígbà ti mo bínú díẹ̀, wọ́n ran ìparun lọ́wọ́ láti tẹ̀ṣíwájú.’

Sekaráyà 1

Sekaráyà 1:13-21