Sefanáyà 2:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Nítorí pé, a ó kọ Gásà sílẹ̀,Áṣíkélónì yóò sì dahoro.Ní ọ̀sán gangan ni a ó lé Áṣídódù jáde,a ó sì fa Ékírónì tu kúrò.

Sefanáyà 2

Sefanáyà 2:1-6