kí a tó lé yín kúrò bí èrò ìyàngbò ọkà,kí gbígbóná ìbínú Olúwa tó dé bá a yín, kíọjọ́ ìbínú Olúwa kí ó tó dé bá a yín.