Sáàmù 99:4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Olúwa tóbi lọba, ó fẹ́ òdodo ó dá ìdọ́gba sílẹ̀;ìwọ ṣe ohun tí ó tọ́ àti ohun tí o yẹ nínú Jákọ́bù.

Sáàmù 99

Sáàmù 99:1-5