Sáàmù 99:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa jọba;jẹ́ kí ayé kí ó wárìrìo jòkòó lórí ìtẹ́ kérúbùjẹ́ kí ayé kí ó wárìrì.

2. Olúwa tóbi ní Síónì;o sì ga jù gbogbo orílẹ̀ èdè lọ.

Sáàmù 99