Sáàmù 97:2-5 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

2. Ojú ọ̀run àti òkùnkùn yí káòdodo àti ìdájọ́ ni ó ṣe ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìtẹ́ Rẹ̀.

3. Iná ń jó níwájú Rẹ̀. O sì ń jó àwọn ọ̀ta Rẹ̀ yíká kiri

4. Ìmọ́lẹ̀ Rẹ̀ tàn ó sí kárí ayéayé rí i ó sì wárìrì

5. Òkè gíga yọ́ gẹ́gẹ́ bí ìda níwájú Olúwa,níwájú Olúwa gbogbo ayé.

Sáàmù 97