Sáàmù 97:1-4 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa jọba, jẹ́ kí ayé kí o yọ̀jẹ́ kí inú ọ̀pọ̀lọpọ̀ erékùṣù kí ó dùn

2. Ojú ọ̀run àti òkùnkùn yí káòdodo àti ìdájọ́ ni ó ṣe ìpilẹ̀ṣẹ̀ ìtẹ́ Rẹ̀.

3. Iná ń jó níwájú Rẹ̀. O sì ń jó àwọn ọ̀ta Rẹ̀ yíká kiri

4. Ìmọ́lẹ̀ Rẹ̀ tàn ó sí kárí ayéayé rí i ó sì wárìrì

Sáàmù 97