Sáàmù 95:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Ẹ wá, ẹ jẹ́ kí a kọ orin ayọ̀ sí OlúwaẸ jẹ́ kí a kígbe sókè sí àpáta ìgbàlà wa.

2. Ẹ jẹ́ kí a wá sí ìwájú Rẹ̀ pẹ̀lú ọpẹ́kí a sì pòkìkí Rẹ̀ pẹ̀lú ohun èlòorin àti ìyìn.

Sáàmù 95