Sáàmù 90:1-3 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, ìwọ ti jẹ́ ibùgbé wa ní gbogbo ìrán dé ìran.

2. Kí a to bí àwọn òkè nlaàti kí ìwọ tó dá ilẹ̀ àti ayé,láti ayérayé dé ayérayé ìwọ ni Ọlọ́run.

3. Ìwọ yí ènìyàn padà sí erùpẹ̀,wí pé “padà sí erùpẹ̀, ìwọ ọmọ ènìyàn”.

Sáàmù 90