Sáàmù 88:1-2 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

1. Olúwa, Ọlọ́run tí o gba mí là,ní ọ̀sán àti ní òru ni mo kígbe sókè sí Ọ.

2. Jẹ́ kí àdúrà mi kí o wá sí iwájú Rẹ;dẹ etí Rẹ̀ sí igbe mi.

Sáàmù 88