Sáàmù 85:1 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

Ìwọ fi ojú rere han fún ilé Rẹ, Olúwa;ìwọ mú ohun ìní Jákọ́bù bọ̀ sí pò.

Sáàmù 85

Sáàmù 85:1-3