Sáàmù 80:17-19 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

17. Jẹ́ kí ọwọ́ Rẹ kí ó wà lára ọkùnrin tí ó wà ní ọwọ́ ọ̀tún Rẹ,ọmọ ènìyàn tí ìwọ tí gbékalẹ̀ fún ara Rẹ.

18. Nígbà náà àwa kí yóò yípadà kúrò lọ́dọ̀ Rẹ;mú wa yè, àwa o sì máa pe orúkọ Rẹ.

19. Tún wa yípadà, Olúwa Ọlọ́run;kí ojú Rẹ̀ kí o tan ìmọ́lẹ̀ sí wa,kí á ba à lè gbà wá là.

Sáàmù 80