Sáàmù 8:8-9 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

8. ẹyẹ ojú ọrun,àti ẹja inú òkun,àti ohun tí ń wẹ nínú ipa òkun.

9. Olúwa, Olúwa wa,Orúkọ Rẹ̀ ti ní ìyìn tó ní gbogbo ayé!

Sáàmù 8