Sáàmù 8:4-6 Bíbélì Mímọ́ ní Èdè Yorùbá Òde Òní (BMY)

4. kí ni ènìyàn tí ìwọ ń rò nípa Rẹ̀,ọmọ ènìyàn tí ìwọ ń ṣe ìtọ́jú Rẹ̀?

5. Ìwọ ṣeé ní onírẹ̀lẹ̀ díẹ̀ ju ẹ̀dá ọ̀run lọìwọ sì dée ní adé ògo àti ọlá.

6. Ìwọ mu-un jọba lórí gbogbo iṣẹ́ ọwọ́ Rẹ;ìwọ si fi ohun gbogbo sí abẹ́ ẹsẹ̀ Rẹ̀:

Sáàmù 8